Sunday, January 24, 2010

'FORITI, MA SORETINU' lati owo Adesina Ogunlana

Gbogbo ara wa eeyan kun fun kiki ede. Gbogbo ara la fi npede, lopolopo ki se ahọn wa nikan. Fun apere, ti oju wa ba pade pin, ede to nsọ ni eru. Ti won ba sana, ibinu ni wọn so yen. Ti wọn ba si yi fẹrẹfẹrẹ, ako fe mo abo niyen. Ti ereke wa ba ga soke to wa tuka, o nsọrọ idunnu ni. Nigbati owó wa, koda ese wa ba gbon laigbaşe lọwọ wa ede wọn ni itiju.

Nigbati awo wa ba pe eru jeje lede, oun a sunki tabi ko kako. Nigbati igba aya wa ba sa mesan, mewa soke sodo, oun to n pe lede ni igbonara. Orun wa pe “irewesi” lede nigba ti wọn ba sori wa kọ dooro. Nje idi eyi ko ni awon baba nla wa fi so pe “Ibanuje sori agba kodo?”


Opolopo agbejọ ro lo wa to nlọ kiri pelu ọrun to sọ ko kọndọrọ. Aye ti su won. Awon lọya ti won ti sọreti nu yi ko da bi G.I Gudijefu, agbonsasa agba imule ilu Rosia kan to le ta ęrupe fun Kemberi asale lati yọ ninu isoro. Awon lọya alaini ireti yi ko ti rọgbọn da si wahala atije, atimu, ani se, wahala aiyeraiye tin se wahala ati lowo lọwọ.Ba wa na ti mọ, işoro nla ni lati gbe ni olowogbowo lai lowo lọwọ. Aisi owo ni aisi irọrun, koda oun ni aisi igbadun.

Nitori na ni awon lQya tQrQ ba wi yii won sip o, fin ronu ati fisę silę. Gęgębi agun banirQ ni Semba owo ijekara ni won ri gba. Bi won si je aladase, oye kanka lai si ola pelu ile ise won ile-abere wo bi ile ekute nikan ni wQn ni. Won o rise gba! Won o lQwo lQwo, ayo jina si won!

Leredi eyi bii malu to bu ku tan, won sorikQ kiri. Sugbon imQran mi nipe – Eyin ara, EFORITI, E MA SORETI NU. Eredi ti ę fin lati foriti? Idi ni pe ti ęyin ba foriti ti ę si padi Qrę da lori eto ise amuse, eyin o ję rere ilę yii.

Eleyi kii se nnkan aleeba, bi eyin se le ma lero bayi. Awon loya tie yin n ka kun gęgębi alaseyege, kuku le ma dara ju yin. Lati bo ninu ajakulę eni lati kQ lati tun ra yin da. A wulo ti ę ba wa iwe mi PGR x BM = S2 UNDERSTANDING THE SECRETS OF SUCCESSFUL LAWYERS(MIMO AŞIRI AWQN ALAŞEYEGE LQYA) ka ati awQn iwe asQniji miran bęę.

Ranti pe ko si ęni ti Aseda pinnu airise fun. Beleyi ba je bee aje pe airise re ki se ti kadara bi wo ti le ma ro.

Ma sQ reti nu. Ma jawQ!

SQ pe o nigba. Sope agbędo! FORITI, MASORETINU.

ENGLISH TRANSLATION OF ABOVE AT: http://www.winnersdonotquit.blogspot.com